Hey Pressto Conference 2021

Just another My Sites site

Yorùbá

Hey Pressto! jẹ́ àpèjọ ClassicPress àti WordPress tí ó wáyé lóri Twitter.

Hey Pressto! àwọn àbájáde jẹ́ àkópọ̀ túwítì bi mẹ́ẹ̀dogun, àtẹ̀jáde ọ̀kan fún ìṣẹjú kan.

Hey Pressto! nírètí àti pinnu láti jẹ́ àpèjọ ìraayèwọlé jùlọ tí a lè jẹ́. Tí o bá lè ríi àwọn ọ̀nà láti ṣàmúgbòòrò  ohun ti a ń ṣe, jọ̀wọ́ jẹ́ kí a mọ̀.

Hey Pressto! ń o nífẹ̀ láti gbọ́ nípa ojú òpó rẹ tàbí àwọn ìrirí. Ǹjẹ́ o ní ojú òpó tí o ní àwọn ìfiṣọwọ́ mílíọ́nù kan? Ìyàlẹ́nu, jọ̀wọ́ sọ díẹ̀ sii fún wa. Ǹjẹ́ o ni ojú òpó tí ó ní ìfiṣọwọ́ ọlọ́gbọ́n? Ìyàlẹ́nu, jọ̀wọ́ sọ díẹ̀ sii fún wa! Ṣe àtẹ̀jáde ìfiṣọwọ́ rẹ àkọkọ́? Ìyẹn jẹ́ ìyàlẹ́nu, bákan náà! Jọ̀wọ́ sọ fún wa díẹ̀ sii. Bí o bá ti ṣe ohunkóhun. Ìyẹn jẹ́ ìyàlẹ́nu! Jọ̀wọ́ sọ fún wa díẹ̀ sii.

Hey Pressto! ó wà fún àwọn ènìyàn tí o ńlo ClassicPress tàbí WordPress láti ṣe ohunkóhun ní gbogbo ìgbà. Ó wà fún àwọn olùmúgbèrú tí ó ń jẹ́kí ìyàlẹ́nu ṣẹlẹ̀, fún àwọn ènìyàn tí o ń ṣe àwọn ìpàdé àti àwọn ìṣẹlẹ̀, fún àwọn ènìyàn tí ọ̀rọ̀ kàn nípa ìṣèjọba. Ṣùgbọ́n ju ohunkóhun lọ, ó wà fún ọ.

Hey Pressto! Mo mọrírì pé a ń gbé nínú ayé kan tí o ní ọ̀pọ̀ àìdọ́gba ìgbékalẹ̀, àti pé a kò lè ṣe àtúnṣe àwọn wọ̀nyíi fúnra wa. A fẹ́ láti jẹ́ ìṣẹlẹ̀ tí o ṣe ayẹyẹ ìmọ̀ láti àwọn ààyè lábẹ́-àṣojú àti àwọn ohun tí a kò kọbiarasí.

Hey Pressto! ń ṣiṣẹ́ fún wákàtí méjìlá, nítorí náà ní ìrètí pé wà ní àkókò díẹ̀ láti darapọ̀ mọ́ tàbí ṣàfihàn níbikíbi tí o wà ní àgbayé.

Hey Pressto! ṣe ìtẹwọ́gbà àwọn ifàkalẹ̀ àti àwọn àbájáde ní èyikéyì èdè.

Hey Pressto! mọ̀ pé Twitter kìíṣe ààyè ńlá fún gbogbo ènìyàn, àti pé a ti ní àwọn àkoólẹ̀ aláìlórúkọ fún àwọn ènìyàn láti ṣàfihàn pẹ̀lú bí wọ́n bá fẹ́.

Hey Pressto! ní iṣẹ́ ọ̀fẹ́ àti ìkọ́ni aláìlórúkọ tí ó lè lò tí o bá nílò ìrànlọ́wọ́ díẹ̀ nínu ifàkalẹ̀ rẹ.

Hey Pressto! àwọn ìfàkalẹ̀ jẹ́ ọ̀nà kíkọ ọ̀rìnlúgba ní gígùn – bíi tuwítì kan.

Hey Pressto! yóò nífẹ̀ kí o ṣàbẹ̀wò sí ojú-ìwé ìfàkalẹ̀ wa (https://2020.heypresstoconf.org/submit/ ). Jẹ́ kí a rii bóyá a lè ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ọ láti pín ìrirí, ìmọ̀ àti ìtàn rẹ.

Hey Pressto! mo nírètí pé wa darapọ̀ mọ́ wa.

Hey Pressto! mo nírètí pé ìwọ yóò sọ fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ nípa Hey Pressto!

Hey Pressto! o ṣeun fún kíka èyí. Ṣe àbojutó ararẹ kí o sì ní ọjọ́ tí ó dára.

Hey Pressto Conference 2021